Isẹ Ọna

 1. Video content

  Video caption: Wole Soyinka gba BBC Yorùbá lálejò nínú igbó kìjikìji tó kọlé sí

  Báa ṣe ń bi í nípa Soyinka lòun náà ń tọ́ka sí Soyinka kan nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀.

 2. Baba Ijesha Saga: Àwọn ọlọ́pàá máa yọ Baba Ijesha látimọ́lé lálalẹ́- Princess

  Ó ni ọ̀rọ̀ tí kò ni ìtumọ̀ rárá ni ọmọbinrin náà ń sọ nítorí ọ̀nà wo ni ó fi mọ̀ pé irú nǹkan bẹ́ẹ̀ wáyé, ṣé àwọn méjèjì ni Baba Ijesha ń bá sùn papọ̀ ní?

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Tope Alabi yà mí lẹ́nu gan o pé "Oniduro mi" kìí ṣe orin tó yẹ kí ọlọ́run fún mi - Tolu Ad

  Olorin ẹ̀mi tó gba imisi to si tun kọkọ kọ orin "Oniduro Mi" ní Tope Alabi tí àwọn n wo loke gẹgẹ bi ọga orin ẹmi ya ohun lẹnu gidi.

 4. Video content

  Video caption: Olamide Ogunade Charcoal artist: Bí mo ṣe ń lo ẹrọ ayélujára fi ran títa àwòrán mi lọ́wọ́

  Iyalẹnu ni wipe ikọwe pencil ati eedu ni Olamide Oguande fi n ya awọn aworan rẹ.

 5. Video content

  Video caption: Professor Peller: A ti gbé iṣẹ́ idán lọ sí ìdá mẹ́rion gbogbo àgbálayé - Alhaja Silifat Ab

  Iyawo gbajugbaja Ọlọwọ idan laye igba nni, Professor Peller dahun ọpọlọpọ ibeere awọn eeyan nipa ọkọ rẹ loju BBC Yoruba.

 6. Video content

  Video caption: Alapinni Oosa ṣàdúrà fún gogbo ọmọ kúoótù, oò jíire bí?

  Ogbontarigi àgbà òṣèré, Ganiu Nafiu ti gbogbo ayé mọ̀ sí Alápinni Ooṣa ti súre ọdún fún kóówá.

 7. Ọjọ́ tí idá yíwọ́ fún ọkọ mi-Ìyàwó Prof Peller

  Lady Peller ni bó tilẹ̀ jẹ́ pé, Professor Peller ku', idán kò kú o torí ó ni ọmọ kan tó ń jẹ́ Zeeto Peller, agbẹjọrò ni, sùgbọ́n òun náà gbówọ́ nínú idán pípa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 8. Video content

  Video caption: Bariga Children Theatre: Ṣeun awobajo sọ ìwúrí rẹ̀ tó fi ń kọ́ àwọn ọmọdé níṣẹ́ẹ Tíátà

  "Tẹ́lẹ̀ mo máa ń ṣa iké ìdọ̀tì ká lè fi jẹun ṣùgbọ́n láti ìgbà tí mo ti darapọ̀ mọ́ Tíátà ọmọdé, ayé mi ti ní ìtumọ̀".