Ọgbọn inu atọwọda

  1. Video content

    Video caption: Pottery: Àwọn onímọ̀ nípa amọ̀ wúlò púpọ̀ ju ike àbí irin lọ

    Awọn eeyan to n fi isẹ amọ mimọ se isẹ se wa rọ awọn ọdọ lati ya si idi isẹ amọ tori owo wa nibẹ.

  2. Video content

    Video caption: DFL: Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí tún ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ girama ní iṣẹ́ Asoná, bàtà àti báágì ṣíṣe

    Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ DFL ló ń wáyé nílé ẹ̀kọ́ girama fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìnrin láti ní iṣẹ́ ọwọ́ yàtọ̀ sí ẹ̀kọ́ ìwé.