Ẹtọ Awọn ẹranko

 1. Yoruba Nation

  Akukoro ẹgbẹ naa, George Akinola, lo sọ bẹẹ ninu ifọrọwerọ kan pẹlu BBC Yoruba.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Snail Slim Soap: Wo ọ̀pọ̀ àǹfààní tó wà nínú lílo ọ̀ṣẹ tí wọn fi omi ìgbín ṣe láti fọ ojú?

  Iwadii kan ree to sọ nipa ọpọ anfaani to wa nidi lilo omi ara igbin to n yọ, fi se ọsẹ lati fi fọ oju rẹ.

 3. Ooni

  Agbegbe Capetown ni awọn ọọni ti salọ kuro nibi ti wọn ti n ṣin wọn, ti wọn ko si mọ iye awọn ti wọn ti n wa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Ọlọ́pàá ti kó àjá méjèèjì lé Lady gaga lọ́wọ́ sùgbọ́n ẹni to n kó wọ́n háde si wà nilé ìwòsàn.

  Sáájú ni Lady Gaga ti jẹ́ẹ́jẹ́ pé òun yóò fún ẹni kẹni tó bá ri àwọn àjá náà ni ($500,000) (#241,000,000) gẹ́gẹ́ bi ẹbùn.

  Kà Síwájú Síi
  next