Katakara lori itakun agbaye

 1. Video content

  Video caption: Kiki Osinbajo: T;o bá yá owó lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni, máa gbìyànjú láti da padà

  Kiki Osinbajo, tii se ọmọ igbakeji aarẹ, Yemi Osinbajo ba BBC Yoruba sọrọ nipa bo se bẹrẹ okoowo lai naani pe amofin ni oun.

 2. CBN

  Banki apapọ lorilẹede Naijiria, CBN ti fi lede ọna ti awọn eniyan le gba lati ri owo ayalọ fun awọn eniyan ti ajakalẹ Boko Haram ṣe ipalara fun ọrọ aje.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Oba Tejuosho

  Wọn ni ẹsun jẹ nkan to doju ti gbogbo ilu ti wọn si fi kun pe Adetokunbo Tejuosho ko yẹ lẹni a yan sipo olori ilu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Covid-19 Pandemic funeral: A dáná sun odidi òkú èèyàn gẹgẹ bí àwọn mọlẹbí ṣe sanwó ẹ̀

  Àwọn ǹkan táa rí rí tẹlẹ tó máa ń ṣẹlẹ níbi ìsìnkú ni Bolanle Okusanya, Elétò abániṣayẹyẹ ìsìnkú sọ síta yìí.

 5. Video content

  Video caption: Paystack Shola Akinlade: Ìgbésẹ̀ 5 yìí ni mo gbé tíléeṣẹ́ Stripe fi dókòwò $200m pẹ̀lú mi

  Onimọ nipa eto idokowo lori ayelujara, to tun jẹ oludari ileesẹ Paystack Shola Akinlade salaye bo se lu aluyo lori ayelujara nidi okoowo fun BBC.