Eto Idanilaraya

 1. Ọdunlade gbe Sanyẹri soke.

  Ilu Ibadan ti n gbalejo awọn gbajumọ osere tiata to wa se ipade apapọ ọlọdọọdun wọn, nibiti wọn yoo ti yan awọn oloye ẹgbẹ tuntun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Sola allyson, olori Ẹmi ni aala gbọdọ wa lori ohun ti awọn ololufẹ̀ olorin lee ṣe si wọn.
 3. Video content

  Video caption: Tomi Waziri: Bí mo ṣe fẹ́ yọ fóònù kí n fún un ló yìnbọn lù mí lójú

  Ọ̀dọ́kùnrin yìí ń retí láti lọ ṣe àgúnbánirọ̀ láìpẹ́ yìí.