Ẹsin Musulumi

 1. Oluwo tilu Iwo

  Oluwo wa woye pe Orisa bibọ ni isoro ilẹ Yoruba, ki agbara si to le wa silẹ Kaarọ Oojire, a gbọdọ dẹkun orisa bibọ, orisa ko gbọdọ wa si aarin ọba.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Sheikh Nuru Khalid

  Sheikh Nuru Khalid ni apakan orilẹ-ede yii ni tiwa, apakan to ku, janduku lo n ṣakoso rẹ, kò sí sí ohun tó ń jẹ́ jàndùkú tẹ́lẹ̀ kí Buhari tó gorí àléfà.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Awọn ọmọ orilẹede Afghanistan n rọ mọ baalu Amẹrika to fẹ fo

  Amofin Dele Farotimi ni ijọba Naijiria ko sa ipa rẹ to bo ṣe yẹ lati kapa awọn jaduku, awọn ọdaran Fulani darandaran atawọn ajinigbe.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Plateau Killing

  Saaju ni Gomina Simon Lalong ti kọkọ pe fun konileogbele ni ijọba ibilẹ mẹta lọjọ Satide nitori wahala to waye ni opopona Rukuba ni ijọba ibilẹ Jos North.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Working religious women: Ẹ̀lẹ́hàá kìí ṣe ọ̀lẹ- Aminat Adegoke

  Ẹ̀lẹ́hàá Aminat tó ṣ ṣe bàtà rán BBC níṣẹ́ sí ògidì ọmọ Oodua tó mọ rírí iṣẹ ọwọ́ pé àtẹ́lẹwọ́ ẹni kìí tan ni jẹ.