Orilẹede Kenya

 1. Wolii TB Joshua ati Jackson Seyonga

  Ni kete ti Pasitọ Seyonga gbọ nipa iku Joshua lọjọ Aiku lasiko isin to n lọ lọwọ nile ijọsin rẹ, eyi ti wọ̀n n fi ẹrọ ayaworan ka silẹ, lo n fo fayọ pe eeyan ibi jade laye.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Mike Sonko

  Bi o tilẹ jẹ pe Mike Sonko lo ni owo rẹ amọ ọpọ eeyan ni ẹnu n ya nipa awọn dukia rẹ to jẹ kikida goolu olowo iyebiye, nigba ti ebi n pa ọpọ eeyan.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: African Eye: Wo Jane Mugo, obìnrin bíi ọkùnrin tó ń ṣiṣẹ́ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ bíi James Bond

  Ẹka ikọ atọpinpin BBC ṣe iwadii akọni obinrin, Jane Mugo, to n fi iṣẹ́ ọtẹlẹmuyẹ aladani yanju aimọye iwa ọdaran laarin ọpọ ewu.