Ipinlẹ Bauchi

 1. Awọn afurasi to se ariya ibalopọ ati onihooho

  Agbẹnusọ fun ileesẹ ọlọpaa ni Bauchi, Wakil Ahmed lo sisọ loju ọrọ yii lasiko to n safihan awọn afurasi naa fawọn akọroyin l‘Ọjọru.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Oluranlọwọ

  Laipẹ yii ni iroyin jáde pé gomina ipinlẹ Bauchi yan Balaraba Ibrahim, si ipo oluranlọwọ pataki lori ọrọ awọn to ti kọ ọkọ tabi iyawo wọn silẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next