Ipese Aabo fun ilu

 1. EndSARS Panel Lagos

  Onidajọ Doris Okuwobi to jẹ alaga igbimọ naa sọ pe ₦410 miliọnu ni awọn fi san owo itunu fun olùpẹ̀jọ́ 71 ti ọlọpaa da lóró.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Endsars

  Ogunjọ, Osu Kẹwaa, ọdun 2021 ni awọn ọdọ ṣe ifẹhọnuhan ni agbegbe Lekki tako ifiyajẹni ati iṣekupani awọn ọmọ Naijiria gba ọwọ awọn ọlọpaa ni Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Kogi

  Ẹni to n salaye nkan to ṣẹlẹ ninu fidio naa ni ọkan lara awọn ero inu ọkọ ni wọn fẹ gba 25000 naira ni ọwọ rẹ, pẹlu ẹsun pe o ji laptop to wa ni ọwọ rẹ ni.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Awọn ọlọpaa n gbaradi

  Igbesẹ naa ṣe pataki lẹyin ti wọn ṣe ọfintoto awọn wahala to lee fẹ bomipana alaafia lasiko idibo sipo gomina to n bọ lọna nipinlẹ Anambra.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Awọn akẹkọọ ti wọn na

  Ile igbimọ aṣofin naa rọ ijọba lati kesi awọn ti ọrọ naa kan ki wọn fi ijiya to tọ jẹ ẹnikẹni tabi ileeṣẹ to ba n ṣe iru tabi hu iru iwa bẹẹ ni ipinlẹ Kwara.

  Kà Síwájú Síi
  next