Ipinlẹ Oyo

  1. Video content

    Video caption: Oyo Schools: Akẹ́kọ̀ọ́ Fásitì, Poly wà nílé, kí ló mú ti alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, girama wà níta?

    BBC Yoruba bọ sigboro lati mọ ero awọn araalu lori bi ijọba ipinlẹ Ọyọ se si ilẹẹkọ pada,ta si se akojọpọ ero obi ati olukọ̀ nipa rẹ́.