Ipinlẹ Kebbi

 1. Kebbi

  Ọmọ ogun ilẹ̀ Naijiria fi ikede naa sita pé wọn ti doola ẹmi akẹkọọ ati olukọ mẹrin lara awọn ti oniṣẹ ibi jigbe ni ipinlẹ Kebbi.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Aga ileewe

  Agbẹnusọ kan fun ijọba ipinlẹ naa ṣalaye fun BBC pe awọn ti bẹrẹ si n ka awọn akẹkọọ to ku ki wọn le mọ iye akẹkọọ ti wọn ji gbe lọ ni pato.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Jubril ti wọn so mọ ewurẹ.

  Ileesẹ ọlọpaa nipinlẹ Kebbi, ti mu ọkunrin kan ati iyawo rẹ meji, fun pe wọn so ọmọ orogún wọn, Jubril Aliyu pọ mọ ewurẹ fun ọdun meji.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Mohammed Jamil Bello

  Ọjọ́bọ̀ ọ̀sẹ yii ni Mohammed Jamil Bello kù gìrì sí ààrẹ Buhari ní ìlú Argungu, ní ìpínlẹ̀ Kebbi, tawọn kan si lo fẹ pa aarẹ ni.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Muhammadu Buhari ati gomina ipin Kebbi, Atiku Bagudu nibi ti iṣẹlẹ naa ti waye

  Ọjọbọ ni fidio kan gba ori ẹrọ ayelujara kan, eyi to ṣafihan bi ọkunrin kan ṣe sare lọ sibi ti Aarẹ Buhari wa, to si 'pakuru mọ Buhari.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Muhammadu Buhari n gbe ami ẹyẹ fun Atiku Bagudu

  Amẹrika ni awọn isẹlẹ yii lee sokunfa ede aiyede ti yoo sediwọ fun ifọwọsowọpọ laarin Naijiria ati Amẹrika lati gba owo ti Abacha ko wa soke okun.

  Kà Síwájú Síi
  next