Iwa Ijẹkujẹ

 1. EFCC Raid: Gbájúẹ̀ 56 ni ọwọ́ tẹ̀ ni òtẹ́lì àti àwọn bùba mííràn nípìnlẹ̀ Ogun

  Àbẹ̀wò àwọn oníròyìn sí ilé ìtura náà lọ́jọ́ ajé ṣe afihàn àwọn tó gba yàra sí ilé ìtura náà si n duro ka ni èjèèjì tí wọ́n sì ǹ sọ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ to wáyé.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. SERAP

  SERAP fi ọrọ yii lede lasiko ti wọn gbe iwadii jade lori ẹsun iwa ibajẹ ni ẹka eto ilẹra, eto ẹkọ ati omi to n sakoba fun awọn ọmọ Naijiria kalẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Muhammadu Buhari

  Aarẹ Muhammadu Buhari ni ijọba òun ti ti mu ki alaafia jọba ni agbegbe Niger-Delta, ta si ti gba ọpọ ilẹ lọwọ awọn adunkookomọni to wa lẹkun ila oorun ariwa Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Femi Falana and Abba Kyari

  Ileesẹ ọtẹlẹmuyẹ Federal Bureau of Investigation, FBI, kede ni oṣu Keje pe Kyari gba owo riba lọwọ gbajúmọ afurasi onijibiti, Ramoni Igbalode Hushpuppi.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Jacob Zuma

  Ile ẹjọ to ga julọ ni Jacob Zuma fi aake kọri lati yọju siwaju igbimọ olugbẹjọ kan to n tanna wadi ẹsun iwa ajẹbanu ti wọn fi kan nigba to wa nipo aarẹ orilẹede naa.

  Kà Síwájú Síi
  next