Agbara to see sọdọtun

 1. Epo bentiroolu

  Atẹjade kan ti akọwe apapọ fẹgbẹ PTD fisita n awọn ko ni fa ṣẹyin ninu gigunle iyanṣẹlodi naa lakọtun, ti ijọba ko ba ṣe awọn ohun ti wọn n beere fun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Water Generator: Ó leè ṣiṣẹ fún wákàtí mẹfà, kó tó sinmi

  Ọmọ Naijiria kan ti se ẹrọ amunawa gẹnẹratọ to n lo lita omi kan lati fi sisẹ, eyi ti owo rẹ ko ga ju ara lọ.

 3. Osisẹ amunawa to wa lori opo

  Ileesẹ amunawa ni Eko buwọ lu iwe adehun kan laipẹ lati mu ki awọn olugbe kan ni Magodo Estate maa gbadun ina ọba amọ kii ṣe ọfẹ lo ba de.

  Kà Síwájú Síi
  next