Aworan Fiimu

 1. Oyin Elebuibon

  Gbajugbaja oṣerebinrin, Oyinkansola Elebuibon ti pariwo sita lori bi awọn eeyan kan ṣe n dẹyẹ si awọn ẹlẹsin abalaye.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Iboji Funmi Martins

  Ashabi Olorisha lo gbe fidio kan soju opo Instagram rẹ lati salaye fun awọn eeyan to n sọrọ odi si pe o gbe fidio bo se tun iboji Funmi Martins se sori ayelujara.

  Kà Síwájú Síi
  next