Orilẹede Uganda

 1. Flo Webber stands amongst the debris of her home on the nearly destroyed island of Barbuda which was nearly levelled when Hurricane Irma made landfall with 300km/h winds.

  Ipe wọn yii wa bi ajọ isọkan agbaye se n pinu lati gbe awọn iwadii wọn sita lọjọ aje paapaa julọ nitori bi ayipada oju ọjọ ṣe n peleke si.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Yemisi Oyedepo

  Broadcast Journalist

  Àìrìjìnà ni àìrábuké ọ̀kẹ́rẹ́, orí ọ̀kadà ni wọn fi gboku lọ mọ́súárì

  Kasirim ni ọ̀pọ̀ ìgbà , ìrìnàjò yìí má n tó wákàtí márún si mẹ́wàá, kò sí ẹbi òkú ti yóò ni ànfàni láti tèlé òkú náà.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Kọndọọmu

  Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Uganda gbé ìjọba àti àjọ aládáni kan lọ sílé ẹjọ́ nítorí kọ́ndọ̀ọ́mù tí wọ́n rà tí kò dára.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Africa eye: Ibi gbogbo là ń dáná alẹ́, ìwà jẹgúdújẹrá pa iléeṣẹ́ Spencom run ní Uganda
 5. Ẹni to n se ayẹwo Coronavirus

  Uganda ko tii kofiri Coronavirus amọ minisita feto ilera ti jẹwọ pe ọrọ aje ilẹ naa ko lee gbe iwosan arun yii, to ba fi bẹ silẹ lọdọ awọn.

  Kà Síwájú Síi
  next