Ipinlẹ Kogi

 1. Adebayo Solomon

  Lọjọ Abamẹta lawọn kọlọnbiti ẹda ọhun yinbọn fun Solomon ninu ọkọ rẹ nigba to n rinrin ajo lati ilu Ilorin si Kabba.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Oluwatobi Adeigba, Ọkọ mi ń lọ siṣẹ́ fún àjọ INEC ló kàgbákò ikú - Opó Adeigba

  Ọmọ Naijiria kan ree ti wọn to lọ sinruulu ni ipinlẹ Yobe amọ to lọ ṣe kongẹ iku latọwọ ikọ Boko Haram.

 3. coronavirus

  Oṣu mẹfa gbako ni ijọba fi gbe awọn ileewe tipa lẹyin ti ajakalẹ aarun covid-19 bẹ silẹ lorilẹede Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next