Ààrẹ Muhammadu Buhari

 1. Ganduje ati Dawisu

  Salihu Tanko Yakasai ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Dawisu lórí Twitter ni olùbádámọ̀ràn pàtàkì lórí ètò ìròyìn sí gómìnà ìpínlẹ̀ Kano.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Sheikh Ahmad Gumi pẹlu awọn agbebọn

  Gomina ipinlẹ Ekiti, Kayode Fayemi sọ pe biba awọn janduku agbebọn yii sọrọ wa lara awọn ọna lati wa ojutu si iṣoro eto abo.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Satguru Maharaj ji ati Aarẹ Muhammadu Buhari

  Guru Maharaj ji sọrọ yii nibi apero kan to da lori awọn iṣẹlẹ to n ṣakoba fun gbogbo agbaye bayii lọjọ Abamẹta.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Asia Benin Republic ati Aworan Aarẹ Buhari

  Niṣe lori ayelujara gbona giri giri lẹyin ti ọgọọrọ eeyan n gba ọrọ naa bi ẹni n gba igba ọti lori Twitter ati Facebook lọjọ Satide.

  Kà Síwájú Síi
  next