Ipinlẹ Ebonyi

 1. Adebayo Solomon

  Lọjọ Abamẹta lawọn kọlọnbiti ẹda ọhun yinbọn fun Solomon ninu ọkọ rẹ nigba to n rinrin ajo lati ilu Ilorin si Kabba.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Aworan awọn oluwode to n pe fun ijiyia to tọ fawọn afipabilopọ

  Awọn to mọ nipa iṣẹlẹ naa sọ fawọn akọroyin pe awọn janduku naa yinbọn fun ọdọbinrin keji ni itan rẹ lẹyin to kọ ki wọn fi ipa ba a lopọ.

  Kà Síwájú Síi
  next