Itan

 1. Video content

  Video caption: Badagry: Ojú ọ̀nà àrèmabọ̀ fáwọn ẹrú tó ń lọ sókè òkun

  Èyí ni ojú ọ̀nà àrèmabọ̀ tó wà ní ìlú Badagry fáwọn ẹrú táwọn òyìnbó ń kó lọ sókè òkun láti se iṣẹ́ agbára.

 2. Sapara-Williams

  Sapara Williams tako ofin ọdun 1909, ti ko faaye gba awọn akọroyin lati bu ẹnu atẹ lu ijọba, o ni iwa yii ko si lara ise Yoruba.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Deeper Life Herbalist: Èṣù gangan ni olóòtọ́ ayé yìí, ẹ̀mí mìí gangan máa ń bà lé mi tí mo

  Oluwo Olakunle ni awọn ẹlẹsin ifa kan to n gbe lẹgbẹ ile wọn lo jẹ iwuri fun oun ti ẹsin naa fi wu u.

 4. Video content

  Video caption: E jẹ́ ká lọ sí ìlú mi BBC yìí dá lórí Epe ní bi tí eégún ti ń fi ẹgba dá bírà lára Oba

  BBC Yoruba rìnrìn ajo lọ si epe Ijebu ati Epe Eko lati mu itan ilu yẹn wa fun un ẹyin ololufẹ wa lopin ọsẹ yii.

 5. Video content

  Video caption: Ogbomoso: Ẹ kálọ sí Ajilete láti mọ àwọn ibùdó tó mú kí ìlú náà yàtọ̀

  Lori eto Ẹ kalọ silu mi ni osu yii, ilu Ogbomoso ni BBC Yoruba wa, lati wo awọn ibi pataki to mu ki ilu naa yatọ.

 6. Video content

  Video caption: Ogbomoso: Ẹbọ ọkùnrin àti obìnrin tí kò ní ìbálòpọ̀ rí ni wọ́n rú dènà ogun Fulani

  Ọmọọba Olawuyi Itabiyi ni ẹẹmẹta ni Fulani Alfa Alimi wa si Ogbomoso laye Oba Toyeje Akanni Abaya Oluoyo amọ ọgbọn lo fi le kuro, ko to lọ dira ogun.

 7. Video content

  Video caption: Akomolede ati Aṣa: Kọ́ ẹ̀kọ́ si nípa ààlọ́ nílẹ̀ Yorùbá

  Olukọ wa, Nike aya Bankole ti wa nikalẹ́ lati kọ̀ wa nipa oniruuru aalọ to wa ati itan bi wọn se bẹrẹ pẹlu itumọ wọn.