Babajide Sanwo-Olu

 1. Ifeoluwa Oyeleke

  Agbẹjọro Taiwo Olawanle sọ pe ko tọna fun ijọba ipinlẹ Eko lati ṣe bẹẹ, niwọn igba to jẹ pe ẹjọ naa si wa nile ẹjọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Iya Jumoke n tẹwọ gba ẹbun ile ati owo lọwọ asoju ijọba Eko

  Amugbalẹgbẹ fun gomina Sanwo-Olu ni niwọn igba ti ẹnikẹni ko mọ tẹlẹ pe irufẹ isẹlẹ aburu yii le sẹlẹ, ni gomina Sanwo-Olu se tete seto fun idile naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Protesters at Lekki Gate

  Igbimọ oluwadii lori iṣẹlẹ #EndSARS sọ ninu abọ rẹ to fi sita pe o kere tan eeyan mẹsan an ni wọn ṣekupa nini iṣẹlẹ ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Awọn oṣiṣẹ LASEMA nibi ile to wo ni Ikoyi

  Kọmiṣọnna eto iroyin nipinlẹ Eko, Ọgbẹni Gbenga Omotoso lo fọrọ yii lede lalẹ Ọjọru loju Facebook ijọba ipinlẹ Eko.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Ile to wo ni Ikoyi

  Kọmiṣọna eto iroyin nipinlẹ Eko fidi rẹ mulẹ pe awọn oṣiṣẹ iṣẹlẹ pajawiri si n tẹsiwaju lati ṣawari awọn eeyan labẹ ogiri alapa ile to wo naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Gómìnà Sanwo-Olu ti ṣe àbẹ̀wó sí ibùdó ilé ọlọ́pọ̀ àjà tó wó lágbègbè Ikoyi

  Gomina babajide Sanwo-Olu ti ṣe abẹwo si ibudo ile ọlọpọ aja to wo lagbegbe Ikoyi ni ilu Eko

  Video content

  Video caption: Gomina babajide Sanwo-Olu ti ṣe abẹwo si ibudo ile ọlọpọ aja to wo lagbegbe Ikoyi

  Gomina Babajide Sanwo-Olu ti ṣe abẹwo si ibudo ile ọlọpọ aja to wo lagbegbe Ikoyi ni ilu Eko.

  Gomina Babajide Sanwo-Olu gba awọn oṣiṣẹ adoola ẹmi to n ṣiṣẹ nibẹ niyanju.

  Gomina Sanwo-Olu n gba awọn oṣiṣẹ adoola ẹmi to n ṣiṣẹ nibẹ niyanju.

  O si ṣalaye pataki ṣẹ ti wọn n ṣe fun ipinlẹ Eko ati paapaajulọ fun awọn ti wọn fẹ doola ẹmi wọn.

  Gomina Sanwo-Olu n gba awọn oṣiṣẹ adoola ẹmi to n ṣiṣẹ nibẹ niyanju.

  Gomina ipinlẹ Eko gba awọn oṣiṣẹ adoola ẹmi to n ṣiṣẹ nibẹ niyanju.

  Gomina Sanwo-Olu n gba awọn oṣiṣẹ adoola ẹmi to n ṣiṣẹ nibẹ niyanju.

  O si ṣalaye pataki ṣẹ ti wọn n ṣe fun ipinlẹ Eko ati paapaajulọ fun awọn ti wọn fẹ doola ẹmi wọn.

 7. Video content

  Video caption: Gomina babajide Sanwo-Olu ti ṣe abẹwo si ibudo ile ọlọpọ aja to wo lagbegbe Ikoyi