Idajọ Iku

 1. Video content

  Video caption: Suicide Prevention: ìwọ́de yìí wáyé láti gbógun ti pípa ara ẹni

  Òní ni àyàjọ́ ìgbógunti pípa ara ẹni láwùjọ ní èyí tí àjọ Glittoh pàrọwà ìforítì àti ìfẹ́ ní ọ̀nà àbáyọ.

 2. Video content

  Video caption: Abiola jẹ́ ẹni tí wọ́n fẹ́ràn káàkiri gbogbo Nàìjíríà

  Àwọn tí ìdìbò àti ìsẹ̀lẹ̀ mánigbàgbé June 12 sọ ìrìrì wọn.

 3. India Cremation: Òkú jíndé nígbà tó ku ìṣẹ́jú péréte ti wọ́n yóò se ètò ìkẹyìn fun

  Súgbọ́n bí ó ṣe ku ìṣẹ́jú pérété tí tí wọ́n yóò ṣáná sí àwọn igi tí wọ́n ti kò fún sísun rẹ̀ ló bá lajú, ìyàlẹ́nu sì ló jẹ́ fún pe ó bá àra rẹ̀ níbí tí wọ́n ti fẹ́ dána sun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Akomolede ati Asa Yoruba: Bí wọ́n bá fi màrìwò ọ̀pẹ lé ara ọkọ̀, ṣé o mọ̀ ìtúmọ̀ rẹ̀?

  Ṣe o gbọ tuntun pe bi o bọ fi kun tabi yọ kuro lara ohun ti wọn fi pa aroko, o ti ba iṣẹ jẹ?