Eto Isuna ara ẹni

 1. Kayode Fayemi pẹlu awọn olukọ

  Gómìnà ìpínlẹ̀ Ekiti, Kayode Fayemi ní òun yóò bẹ̀rẹ̀ sí san ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n náírà owó òṣìṣẹ́ tó kéré jù ní ìpínlẹ̀ náà.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Asia Algon

  Ẹgbẹ́ ALGON kọ ìdá mẹ́tàlélógun ti àwọn gómìnà ti ṣètò fún wọ́n, èyí tó gbe pééli díẹ̀ sí ìdá ogun o lé diẹ̀ ti wọ́n ń gba tẹ́lẹ̀.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Yinka Ayefele ṣe ìṣirò owó tí Dino ná ní ìsìnkú ìyá rẹ̀

  Yinka Ayefele ni eléré tí Sẹ́nétọ̀ Dino Melaye pè fún ètò ìsìnkú ìyá rẹ̀ tó ṣe láipẹ̀.