Awọn ọdọ

 1. Awọn oluwọde EndSARS

  Kamsiyochukwu Ibe ni awọn janduku mẹta to ṣekọlu si oun naa sọ wi pe nitori oun jẹwọ niwaju igbimọ oniwadii ni ipinlẹ Eko ni.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Àwọn ọ̀dọ́ opó l'obìnrin sọ ìrírí wọn l'awùjọ

  Kìí ṣe nǹkan ti o rọrun láti máa dágbé dásọ̀ tí ènìyàn kò bá ni ọkọ ni àwujọ- Àwọn opó

 3. Yemisi Oyedepo

  Broadcast Journalist

  Captain Walz ti kọ́kọ́ bọ́ra sí hòhò l'àdúgbò kí o tó lọ lu Lẹ́ksọrà ní ọja kejì- Baba Captain Walz

  Iṣẹlẹ yi gbode kan loju opo ayelujara tawọn eeyan si n reti igbesẹ ti fasiti naa yoo gbe lori ọrọ yi

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Bobrisky

  Bobrisky ṣalaye lori awọn ikanni rẹ loju opo ayelujara pe ki gbogbo awọn to n waasu fun oun pe ki oun yi igbe aye oun pada o lọ wa ọrọ mii sọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. ABIMBOLA OYEYEMI,

  Agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun, Abimbola Oyeyemi ni awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun nile ẹkọ kan gbinmọ pọ lati da idanwo naa ru tori wọn ko mura lati ṣe idanwo.

  Kà Síwájú Síi
  next