Orilẹede Nepal

  1. Video content

    Video caption: India, Coronavirus: Ìtọ́jú aláìsàn ló jẹ́ mi lógún nítorí ètò ìlera wa mẹ́hẹ- Nọ́ọ̀sì Kama

    Lọwọlọwọ ni orilẹ-ede India atawọn to yii ka n koju iṣoro Covid 19 to n gab ẹbọ lọwọ wọn.

  2. Video content

    Video caption: Ìwé kíkà ló pín ọmọ tálákà yìí àti àwọn òbí rẹ̀ níyà

    Orí òkè ni ìlú ọmọkùnrin yìí wa, ó sì gbọdọ̀ rìn fún ọjọ́ márùn-ún kó tó rí àwọn òbí rẹ̀ tó ti fi sílẹ̀ lọ́dún méjìlá sẹ́yìn.