Kata-kara

 1. Video content

  Video caption: Wikipedia: Ẹ̀nìkan sọ fún mi pé iṣẹ́ ìdọ̀tí ni màá ṣe ni mo ṣe ń ta ìwé

  BBC Yoruba se alabapade ọkunrin kan, Adekola Ademuyiwa, ẹni to sọ awọn iriri rẹ nidi iwe tita lọ̀na awada ati ẹfẹ ati awọn iwọsi to wa nidi okoowo naa.

 2. Video content

  Video caption: Iyalaje Oodua: Toyin Kolade ṣàlàyé ìdí tí Ooni Ogunwusi ṣe fi jẹ Ìyálájé Oodua

  Gbajumọ Oniṣowo, Toyin Kọlade ṣalaye pataki aje ninu itan iṣẹdalẹ Yoruba.

 3. Awọn ọlọja tomato ati alubọsa duro ti ọja wọn

  Ṣaaju ọjọ mẹfa ni wọn kọ lati ko ounjẹ wa si iwọ guusu Naijiria loṣu Kẹta ki Gomina Kogi, Yahaya Bello, to dasi ọrọ naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Epe Fish Market: Wá wo oríṣi ẹja tí o rírí lọ́jà ẹja tó tóbi jùlọ ní Nàíjíríà

  Awọn apẹja wa n kerora bi owo awọn ati ọkọ oju omi ti wọn fi n pa ẹja se gbowo lori

 5. Agodi Gate fire

  Ọpọ sọọbu ti awọn ẹya ara ọkọ olowo iyebiye wa lo jona kanlẹ ninu ijamba ina naa to bẹrẹ ni deede aago mọkanla alẹ ọjọ Ẹti.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Oloye Jimoh Odutola

  Titi di oni, orúkọ Jimoh Odutola ko le parẹ ni ọjà Ogunpa/Dugbẹ nilu Ibadan ati lagbegbe Surulere nilu Eko.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. Video content

  Video caption: Ado Ekiti Blind Couple: Tọkọ-taya Oke ní Ọ́ba òkè ló fi àwọn dá àrà tó wù ú

  Tọkọ-taya Oke wa n rọ awọn eeyan awujọ lati ye ro pe ko yẹ ki iru awọn eeyan to ba ni ipenija bayii jade laye tabi pe o ti tan fun wọn.

 8. Ẹnu bode Naijiria

  Gbadamosi Olusola ni ko si anfaani kankan ti Naijiria jẹ lara titi awọn ẹnu ibode, nitori pe iṣẹ fayawọ lọ soke si, ti ko si tun si ayipada lori ọrọ eto aabo.

  Kà Síwájú Síi
  next