Omoyele Sowore

 1. Omoyele Sowore

  Ṣaaju ni Sowore ati awọn oluwọde kan ti kọkọ korajọ siwaju Unity Fountain laarọ ọjọ Aje lati ṣe ifẹhonuhan lori eto abo to mẹhẹ ni Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Omoyele Sowore laarin awọn ọmọ ikọ Revolution Now niwaju ile ẹjọ

  Amọ ẹgbẹ Amofin Amẹrika ni iti ọgẹdẹ ni awọn ẹsun ti wọn fi n kan Sowore ọhun, ko si to ohun to yẹ ki ijọba apapọ yọ ada si.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Omoyele Sowore laarin ero

  Lasiko igbẹjọ naa si ni igun olupẹjọ se atunse si awọn ẹsun to fi kan Sowore eyi to nii se pẹlu didi ọtẹ lati gba ijọba ati iditẹ lati gbajọba.

  Kà Síwájú Síi
  next