Awọn ọmọde

 1. Awọn akẹkọọ

  Kọmiṣọnna eto iroyin ipinlẹ Eko ni ijọba apapọ lo paṣẹ pe ki awọn akẹkọọ pada sile iwe fun saa eto igbẹkọ tuntun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. awọn akẹkọọ ninu kilaasi

  Alaga ile lori eto ẹkọ, Ọjọgbọn Julius Ihonvbere lo ṣi aṣọ loju eegun ọrọ yii ninu atẹjade kan to fi sita lorukọ igbimọ rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Ọdún mẹ́ta ní àwa 18 fi dá #400,000 tí a fi kọ́ ilé ìwé

  Ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá tí ìjọba àpaọ̀ ń fún wa lósooṣù ni a tí n yọ ẹgbẹ̀rún méjì tí a dá fún ọdún mẹ́ta

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Aworan ẹsẹ ikoko

  Awọn onimọ sayensi ṣalaye pe, iru iṣẹlẹ yii ṣọwọn, ti ko si ju mẹwa lọ to ni akọsilẹ lagbaye ṣugbọn o wọpọ laarin ẹranko.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Ọjọgbọn Wole Soyinka

  Wole Soyinka wa daba sise idanilẹkọ nipa ibọn lilo fawọn agbẹ, ki wọn le fi ọwọ kan mu ọkọ lati roko, fi ọwọ keji mu ibọn, ti yoo fi daabo bo ẹmi ati ire oko rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next