Isẹ Akọroyin

 1. AMuludun FM, Ibadan

  Lara awọn ohun ti wọn bajẹ ni awọn irinṣẹ ti wọn n lo ni ọọfisi, awọn ferese ọọfisi, to fi mọ awọn ọkọ ayọkẹlẹ atawọn dukia miran.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Kemi Olunloyo on Sunday Igboho: Mi ò gbè lẹ́yìn Yoruba Nation àmọ́ mo wà lẹ́yìn Sunday Igb

  Gajugbaja oniroyin ori ayelujara, Kemi Olunloyo sọrọ ilẹ kun.

 3. Awon adigunjale

  Ofin NBC ni "oniroyin ko gbudọ gbe ohun to lee tu ilu ka jade lori afẹfẹ tabi to lee dẹru ba awọn araalu tabi fa ipinya".

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. BCOS

  BBC Yoruba ṣe abẹwo si ileeṣẹ naa ni owuro ọjọ Ẹti, a si ri i daju wi pe ijọba ipinlẹ Ọyọ ti bẹrẹ si ni wo awọn ile kan to jẹ ileegbe awọn oṣiṣẹ BCOS.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. NLC

  Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ ni Naijiria ti ni awn yoo bẹrẹ ifẹhọnu tako igbese awọn asofin lati yi aṣẹ gbedeke owo oṣu oṣiṣẹ pada.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Gebru

  Atimọle akọroyin BBC yii lo n waye lẹyin ti awọn ologun naa ti kọkọ ti awọn eeyan meji to n ṣiṣẹ fun ileeṣẹ iroyin Agence France-Presse, AFP, ati Financial Times mọle.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. Bata awọn akẹ́kọ̀ọ́ ti wọn ji gbe

  Lakotan, onkọwe yii ni bi awọn ileeṣẹ iroyin ilẹ okeere yìí ti n ṣe agbekalẹ iroyin lori awọn janduku ajinigbe ati Boko Haram ṣe pataki.

  Kà Síwájú Síi
  next