Oniruuru Ẹya ati ajọsepọ wọn

 1. BAnji Akintoye ati Igboho

  Ọjọgbọn Akintoye ni "ijọba gba awọn onṣẹ wọnyii lati mọọmọ ba akitiyan ijangbara fun Orilẹede Oduduwa jẹ titi yoo fi di akurẹtẹ".

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Oluwo of Iwo God festival: Mí ò bínú sí àwọn olórìṣà àmọ́...

  Oluwo ti Iwo ni oun ko ni nkankan pẹlu awọn oloriṣa amọ koko ọrọ toun ni pe ki wọn ma ṣe gbe ọba si abẹ wọn.

 3. Babatunde Ọlatunji ni ẹnu iṣẹ ilu lilu

  Babatunde Olatunji di eekan onilu pẹlu awo orin mẹtadinlogun, awo orin rẹ akọkọ to gbe jade lọdun 1959 pẹlu akọle "Drums of Passion" ti ọpọ gboṣuba fun gẹgẹ bi eyi to pe akiyesi awọn alawọfunfun si orin rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Banji Akintoye ati Sunday Adeyemo Igboho

  Apapọ ẹgbẹ awọn to n ja fun idasilẹ Yoruba Nation, Ilana omo Oodua ti fesi si ẹsun igbesunmọmi ti Abubakar Malami fi kan Sunday Igboho.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Awọn isẹlẹ to n da ilu ru

  BBC Yoruba se akojọpọ awọn isẹlẹ akanilaya ti ko ba tun sọ orilẹede yii sinu ogun abẹle keji nibayii ta n sami ọdun Kọkanlelọgọta ti Naijiria gba ominira.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Video content

  Video caption: Oba Ogboni: Ògbóni ìgbà ìwásẹ̀, ROF, Awọpa, Sáàlà... Wá gbọ́ oríṣi ẹ̀ka ìjọ Ogboni tó wà

  Ogboni pọ, ṣugbọn Ogboni igba iwasẹ lo bi awọn to wa kaakiri lode oni.