Awọn ijamba ati awọn iṣẹlẹ eto irinna ofurufu

 1. Ayederu owo naira ẹgbẹrun kan alapapọ

  Agbẹjọro ajọ DSS sọ nile ẹjọ pe laarin oṣu Kinni si oṣu Keje, ọdun 2021, ni awọn eniyan naa, ati awọn akẹẹgbẹ wọn to ti salọ, gbimọpọ lati lu awọn araalu ni jibiti.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Ọ̀pẹlọpẹ́ Ajá tí Ifa ní kí a fi ṣètùtù ní Ekiti ní 1942 ni kò jẹ́ kí ìjàmbá náà pọ̀ jù- Ol

  BBC Yoruba ṣabẹwo sibi ti ijamba ọkọ ofurufu akọkọ nilẹ Afirka ti ṣẹlẹ ni Ikogosi Ekiti lọjọ kejila, oṣu kẹrin, ọdun 1942.

 3. Awakọ baalu to ja laarin awọn ọga ologun

  Oludari ẹka alarina ati eto iroyin fun ileesẹ ologun ofurufu, Edward Gabkwetto ni lọjọ Aiku, ọjọ Kejidinlogun osu Keje ọdun 2021 ni deede aago kan ku isẹju mẹẹdogun, ni isẹlẹ naa waye.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Ogere

  Ileeṣẹ to n risi ọrọ irina ọkọ ni ipinlẹ Ogun ni nkan bi aago mẹfa owuro Ọjọ Iṣẹgun ni ijamba ina naa waye.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Oloogbe Alfred ati Jeniffer aya rẹ

  Obinrin opo naa wa n beere pe bawo ni oun se fẹ se igbe aye oun, bawo ni oun se fẹ da jẹun lai si ọkọ oun nitori awọn dijọ maa n se ohun gbogbo papọ ni.

  Kà Síwájú Síi
  next