Ileesẹ Agbohunsafẹfẹ BBC

 1. Video content

  Video caption: Protein Marasmus: Wo èwu tó wà nínú kí ọmọdé má ní èròjà Protein lára

  BBC se iwadi ohun to n mu kawọn ọmọde maa se aisan lọpọ igba ati ewu to wa ninu rẹ.

 2. Video content

  Video caption: Africa Eye: Ọmọ ìgboro méje tó ń jò tà di aláṣeyọrí

  BBC ní Afirika se iwadii ijinlẹ nipa ikọ awọn ọmọ igboro meje ti ko nile lori fun ọdun meji ati bi ọrọ wọn se ja sọpẹ lẹyin o rẹyin.

 3. Aworan eto Brekete Family

  Ahmed Isah, Ordinary President n tọrọ aforijin lẹ́yin ti fọnran iwadii kan ti BBC ṣe lori iwa rẹ jade, tawọn eeyan si tako iwa rẹ naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Africa Eye: Ahmed Isah rèé tíí ṣe ààrẹ lásán làsàn ní Nàíjíríà tí inú aráàlú dùn sí

  Akọroyin BBC Africa Eye,Peter Nkanga tọpinpin Ahmed Isah ati ikọ rẹ fun ọpọlọpọ ọsẹ lati mọ bi wọn se n gba ẹtọ ọmọ Naijiria le wọn lọwọ.

 5. Video content

  Video caption: Covid-19: Wo ìròyìn òfegè mẹ́jọ táwọn adarí ẹ̀sìn ń sọ nípa àbẹ́rẹ́ àjẹsára Coronavirus

  Oluwadi nipa abẹrẹ ajẹsara to n tako arun Coronavirus ni fasiti Washinton, Kolina Koltai salaye fun BBC nipa ìroyin ofege to lu igboro pa.

 6. Gebru

  Atimọle akọroyin BBC yii lo n waye lẹyin ti awọn ologun naa ti kọkọ ti awọn eeyan meji to n ṣiṣẹ fun ileeṣẹ iroyin Agence France-Presse, AFP, ati Financial Times mọle.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. Video content

  Video caption: Nigerian Fraudsters: Ìwádìí BBC fihàn pé ìdajì àwọn gbájúẹ̀ lágbàyéé wá láti Nàíjíríà

  Onijibiti ti BBC fọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wo ní òun fẹ́ lówó bíi olùdarí Facebook, Mark Zuckerberg ni òun ṣe ń lu jìbìtì.

 8. Fr Ejike Mbaka

  Awọn ọmọ ijọ Mbaka n dunkooko lati pa awọn akọroyin BBC danu nitori pe wọn ni wọn n kọ 'awọn iroyin ti ko dara nipa Fada Mbaka'.

  Kà Síwájú Síi
  next