Orilẹede Yemen

  1. Video content

    Video caption: Yemen Water Child: Ọmọdé 44 ni Sọ́jà pa, tí 100 míì sì kú látọwọ́ ohun ìjà olóró

    Isẹlẹ bi sọja se n pa awọn ọmọde lorilẹede Yemen lo ti n fa rogbodiyan lori ayelujara bayii.

  2. Video content

    Video caption: Mutallab‘s Father: Ọmọ mi ti kábàmọ́ọ̀ ìwà tó wù, ẹ ṣàánú rẹ̀

    Bakan naa ni baba Mutallab tun fi ireti han pe ọmọ oun yoo jade lẹwọn loju aye oun abi lẹyin iku oun.