Orilẹede Zimbabwe

 1. Eto isinku Ginibri

  Ẹnikan to mọ nipa ijamba ọkọ to pa Ginimbi ni, ere asapajude to sa lọjọ Aiku ló mu ki ijamba waye, ti ọkọ rẹ si gbina loju ẹsẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Marry Mubaiwa

  Ìyàwó igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè Zimbabwe yóò fojú ba ilé lónìí lẹ́yìn tí wọ́n fẹ̀sùn ìwà jẹgúdújẹrá kàn án.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Zimbabwe Poverty: Lati ogoji ọdun ni iyàn ti wọn ko ri ri ti m ba wọn ja nilu yii

  Arábìnrin Scholastica sọ bí àìní ṣe wọ̀ ọ́ lọ́wù gidi gan tó bẹ́ẹ̀ tí kò lè yàn láti jẹun kó tún lo oògùn.