Ilẹ Europe

 1. Ọkọ̀ ofurufu àkọ́kọ́ láti ilẹ̀ òkèrè ball si pápákọ òfurufu ilú Eko lọ́san òní

  Ọkọ̀ òfurufu ọhun to gbéra lati Beirut, Lebanon balẹ̀ si pápákọ̀ òfurufú Muritala Muhammed International nílùú Eko ni dede aago méjì kọjá ìṣẹ́jú mẹ́tàdínlógún lónìí sátide.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Awọn aṣatipo lori okun

  Awọn mẹtadinlọgbọn tawọn apẹja doola ẹmi wọn ṣalaye pe, awọn ọmọde marun un wa lara awọn to bomi lọ́nà àtilọ.

  Kà Síwájú Síi
  next