Eṣọ aṣọ

 1. Video content

  Video caption: Snail Slim Soap: Wo ọ̀pọ̀ àǹfààní tó wà nínú lílo ọ̀ṣẹ tí wọn fi omi ìgbín ṣe láti fọ ojú?

  Iwadii kan ree to sọ nipa ọpọ anfaani to wa nidi lilo omi ara igbin to n yọ, fi se ọsẹ lati fi fọ oju rẹ.

 2. Model in Ghana Must Go fabrics

  Ayaworan ọmọ Naijiria, Obina Obioma safihan ọna orisirisi tawọn eeyan le fi sọ baagi bẹmidije ti wọn fi n kẹru lati fi salaye irinajo sise.

  Kà Síwájú Síi
  next