Lilo oogun oloro lati takebe

 1. Zainab Aliyu ninu aṣọ ajọ NDLEA

  Baba Zainab sọ fun BBC pe oun dupẹ lọwọ Eleduwa fun ayipada to ba aye ọmọ oun lẹyin to darapọ mọ ajọ NDLEA tan.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Yemisi Oyedepo

  Broadcast Journalist

  Captain Walz ti kọ́kọ́ bọ́ra sí hòhò l'àdúgbò kí o tó lọ lu Lẹ́ksọrà ní ọja kejì- Baba Captain Walz

  Iṣẹlẹ yi gbode kan loju opo ayelujara tawọn eeyan si n reti igbesẹ ti fasiti naa yoo gbe lori ọrọ yi

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. egbòogi olóró igbo

  Gomina Rotimi Akeredolu gbe imọran yii kalẹ nibi ipade apero kan to waye lori anfaani ati iwulo ọgbin igbo ni Naijiria, eyi to waye nilu Akurẹ lọjọ Aje.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Bisikiiti naa ati awọn afurasi mejeeji

  Ajọ to n gbogun ti oogun oloro ni Naijiria, NDLEA ti tẹ ọmọbinrin kan ati ọrẹkunrin rẹ to n ta ipapanu ti wọn fi oogun oloro ṣe.

  Kà Síwájú Síi
  next