Iseda

 1. Video content

  Video caption: Wole Soyinka gba BBC Yorùbá lálejò nínú igbó kìjikìji tó kọlé sí

  Báa ṣe ń bi í nípa Soyinka lòun náà ń tọ́ka sí Soyinka kan nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀.

 2. Video content

  Video caption: Olamide Ogunade Charcoal artist: Bí mo ṣe ń lo ẹrọ ayélujára fi ran títa àwòrán mi lọ́wọ́

  Iyalẹnu ni wipe ikọwe pencil ati eedu ni Olamide Oguande fi n ya awọn aworan rẹ.

 3. Video content

  Video caption: Owu Water Fall: Ọba Oyewole ni ibùdó ìrìn àjò afẹ́ gidi ni àmọ́ ọ̀nà ibẹ̀ burú jáì

  Ilu Ówù nijọba ibilẹ́ Kajọ̀la nipinlẹ Kwara ni omi iṣẹda to n san naa wa, to si ga ni iwọn ọgọfa mita, eyi to ga julẹ nilẹ Afirika.

 4. Awọn akẹkọọ

  Wo àwọn orílẹ-ede tó ti ṣílẹkún àwọn ilé ìwé padà ní àgbáyé lẹyìn kónílé-ó-gbélé coronavirus àti ohun tó ti ṣẹlẹ níbẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Òkè Ìdànrè: Òkè tó kéré jùlọ jẹ́ ẹsẹ̀ bàtà ẹgbẹ̀rún mẹ́ta

  Ori oke idanre ni awọn eeyan ilu naa n gbe laye atijọ, nibiti ile-ẹkọ, aafin ọba ati oniruuru ile alarabara wa.

 6. Video content

  Video caption: Olumo Rock: Òrìṣà Igùn lọba ọ̀pọ̀ òrìṣà tó wà lábẹ́ Olúmọ tó ń dáhùn àdúrà

  Àwọn iya olorisa labẹ Olumọ tun sọ fun BBC Yoruba pe ti alaisan ba mu omi kan to wa labẹ Olumọ, ara rẹ yoo ya kiakia.