Igbnmọ alaabo labẹ ajọ isọkan agbaye

 1. Video content

  Video caption: BBC Africa Eye: BBC ṣe àyẹ̀wò bí ìjẹkújẹ iléeṣẹ́ ológun ṣe ń ṣàkóbá ìdojúkọ ìgbésùnmọ̀mí

  Orilẹede MAli n koju igbesumọmi awọn alakatakiti ẹsin ní Mali eleyi to si n da omi tutu si ọkan awọn ọmọogun orilẹede naa.

 2. Iba Gani Adams

  Awọn ti Gani Adams kọ lẹta naa si ni Akọwe Agba Ajọ Iṣọkan Agbaye, UN, Alaga Ajọ Iṣọkan ilẹ Africa, AU, Ijọba orilẹede Amẹrika, Akọwe ijọba Ilẹ Gẹẹsi, Iṣọkan Ilẹ Yuroopu ati awọn orilẹede to wa ni abẹ rẹ

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Awọn ọmọ ẹgbẹ IPOB

  CNG ni ko din ni ọtalelẹẹdẹgbẹrun ati mẹwaa, 970 akẹẹkọ ti ajinigbepawo ti ji gbe loke ọya laarin oṣu kejila ọdun 2020 si oṣu kẹrin ọdun 2021.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Muhammadu Buhari

  Amẹrika wa fi iwadii ati bi wọn ti fi ọwọ ofin mu alaga ajọ EFCC to n gbogun ti iwa ibajẹ, Ibrahim Magu lori ẹsun iwa ajẹbanu, ṣe àpẹẹrẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: African Eye: Ìwádìí BBC lórí ikú tó pa ọmọ ogun 26 ní Libya láti ipasẹ̀ Díróònù àìmọ̀dí

  BBC Africa Eye ṣe àwárí rẹ̀ pé, ilẹ̀ United Arabi Emirate UAE ati Egypt lo n fi diroonu sere ọwọ lorilẹede Libya, eyi ti ko jẹ ki ogun sinmi nibẹ.