Orilẹede Tanzania

 1. Samia Suluhu Hassan

  Sugbọn gbogbo amuyẹ yii ko ti i safihan bi yoo ṣe le ṣe ilana ìṣàkóso. Eyi to ṣe koko ni pe boya yoo tẹsiwaju pẹlu ọwọ yẹpẹrẹ ti asiwaju rẹ fi mu ọrọ coronavirus.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Aarẹ John Mugufuli

  Ki John Mugufuli to di aarẹ lo ti gba orúkọ inagijẹ 'Bulldozer' nitori bo ṣe ṣe agbatẹru isẹ akanse atunse oju ọna lasiko to jẹ minisita fun àkànṣe isẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Michelle Obama and Donald Trump give speeches

  Michelle Obama sọ pe ohun to ṣẹlẹ laarin ọdun mẹrin ti awọn lo kọja ni Amẹrika yii ṣoro lati ṣalaye fawọn ọmọ awọn.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. steven

  Steven lo gba alakeji lọ lẹyin to dẹnu ifẹ kọ Antoine ololufẹ rẹ ni àrà ọ̀tọ̀ lábẹ̀ omi láì duro gba èsì bóya Antoine gbọ́ tabi kò gbà.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Coronavirus

  Ijọba ni oun gbe igbesẹ ọhun lati dẹkun bi ọwọja Coronavirus to n ja kiri, eyi to ti mu ki awọn alarun di mẹfa, lati meji to wa tẹlẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next