Ounjẹ

 1. Video content

  Video caption: Rotten Tomatoes: Ìdí tí Tòmátò ẹ̀sà kò ṣe dára fún ìlera yín; wo àwọn kókó márùn-ún yìí

  Awọn Oni-tomato ati ata sọ iriri wọn nipa bi o ṣe maa n bajẹ ati idi ti wọn fi n ta a fun awọn onibara.

 2. Video content

  Video caption: Protein Marasmus: Wo èwu tó wà nínú kí ọmọdé má ní èròjà Protein lára

  BBC se iwadi ohun to n mu kawọn ọmọde maa se aisan lọpọ igba ati ewu to wa ninu rẹ.

 3. Bags of rice

  Aburo Opeyemi, Alima, to wa ninu ṣọọbu ọhun lasiko naa ta irẹsi fun okunrin naa pẹlu igbagbọ pe aburo rẹ ni awọn ọdọkunrin meji ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. NAFDAC

  Ajọ NAFDAC ni awọn ika eniyan to n ta awọn adiye tutu ti wọn n gbe si inu yinyin yii lẹyin ti wọn ba ti fi ''formalin'' si inu rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next