Ilokulo Ọmọde

 1. Rape

  Agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa ni ipinlẹ Nasarawa sọ pe awọn yoo pe Bako Anjeh lẹjọ ni kete ti wọn ba ti pari iwadii awọn lori ẹsun ti wọn fi kan an.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Aworan ibalop ati abo

  Kareem sọ fun BBC Yoruba ninu ifọwerọ kan pe irufẹ ẹni to ba pin fọran bẹẹ le fi ẹwọn ọdun mẹwaa jura tabi ko san owo itanran ogun miliiọnu naira.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Chrisland School

  Lai naani awọn ikilọ ti ijọba fi lede lori fidio ibalopọ laarin awọn ọmọde ni ileẹkọ Chrisland, fidio na jale ja oko lori ayelujara.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Baba Ijesha ati Princess

  Nigba ti afurasi naa ba BBC sọrọ, o ni inu oun ko dun rara nitori iroyin iku akẹgbẹ oun pataki to jade laye, iyẹn, Dejo Tunfulu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Afurasi Ajọmọgbe Olafisoye

  Alukoro fun ileesẹ ọlọpaa nipinlẹ Eko, Benjamin Hundeyin fi idi isẹlẹ naa mulẹ, to si ni agọ ọlọpaa Ojodu ni afurasi naa wa.

  Kà Síwájú Síi
  next