Ikọ Boko Haram

 1. Children

  jọ UNICEF kesi gbogbo awọn ti ọrọ kan lati fi opin si ifiyajẹni awọn ọmọde ati ifipabanilopọ awọn ogo wẹẹrẹ ni Naijiria ati ni ilẹ Afrika ni apapọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. An janduku agbebọn

  Lai Mohamed ni ko dara bi iwe iroyin Economist ṣe sọ pe awọn agbesunmọmi ti ṣe agbekalẹ ijọba wọn lapa ila oorun ariwa Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. ISWAP

  Igba akọkọ ree ti ileeṣẹ ọmọ ogun yoo fidi ọrọ mulẹ pe lootọ ni Abu Musab Al Barnawi ti ku lati igba iroyin nipa iku rẹ ti gbode kan ninu oṣu Kẹjọ, ọdun yii.v

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Nigerian Army

  Aṣoju alukoro ileeṣẹ ọmọ ogun, Bernard Onyeuko lo fi ọrọ naa lede nibi to ti sọ pe awọn mọlẹbi awọn agbesunmọmi naa wa lara awọn eeyan ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Awọn obinrin to jajabọ lọwọ Boko Haram

  Kọmísọ́nà fọ́rọ̀ obìnrin ni Borno ni gbogbo nǹkan tó wà ní ìkápá oun ni oun yoo ṣe láti rán awọ́n obinrin ati ọmọ wẹwẹ naa lọ́wọ́.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Boko Haram

  Iroyin abẹlẹ ni awọn agbebọn naa ṣekọlu si awọn ilu kereje ni ijọba ibilẹ Shiroro, ti wn si n waasu fun awọn eniyan.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. Yan bindiga

  Iroyin ni awọn agbebọn pa awọn ọmọogun mẹtadinlogun ati araalu meji ni opin ọsẹ ni Sokoto, ti wọn si gba isakoso agbegbe Babangida ni ni ipinlẹ Yobe.

  Kà Síwájú Síi
  next