Igbeyawo

 1. Lateef Adedimeji ati Adebimpe Oyebade

  Adebimpe Oyebade ni Lateef Adedimeji ko tii kọ ẹnu ifẹ si oun lasiko ti oun sọ ni gbangba pe kii ṣe ọrẹkunrun oun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Aworan Malala nigba to wa si Naijiria

  Malala ati ololufẹ rẹ, Asser Malik ṣe nikkah wọn nibi ti wọn ti so awọn mejeji pọ ni ilana ẹsin Musulumi.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Princess Mako

  Princess Mako fẹ Kei Komuro to jẹ ọmọ atapatadide, ti yoo si padanu ipo rẹ bii ọmọọba, yii ti kii ṣẹlẹ si awọn ọmọọbakunrin.

  Kà Síwájú Síi
  next