Yoruba

 1. Video content

  Video caption: Yoruba language: Àmì ohùn ṣe pàtàkì nínú èdè Yorùbá

  BBC Yorùbá jáde lọ bèèrè àmì ohùn àti ìtumọ̀ gbólóhùn Adun ni n gbẹyin ewuro lọwọ awọn eniyan.

 2. Video content

  Video caption: Yorùbá tone mark: Fífi àmì ohùn sí orí ọ̀rọ̀ Yorùbá ṣe pàtàkì

  Àwọn òkúnrin fakọyọ púpọ̀ nígbà tí BBC jáde lọ bèèrè àmì orí ọ̀rọ̀ Konko-jabele kódà wọ́n fihàn pe àgbà ọ̀jẹ̀ làwọn!

 3. Aarẹ Gani Adams

  Akanṣe eto abo yii ni iroyin sọ pe o jẹ ajọmọ ati ajọro gbogbo gomina ni ilẹ Yoruba lojuna ati pese eto abo to peye fun mutun muwa kaakari ilẹ naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Àṣà àti ìgbàgbọ́ Yorùbá ni pé òbí wọn máa ń padà wá sáyé

  BBC Yorùbá jáde lọ bèèrè ìdí ti a fi ń sọ ọmọ ni Yetunde ki àwọn èwe ìwòyí lè kọ́ ẹ̀kọ́ síi nípa àṣà àti ìgbàgbọ́ Yorùbá.

 5. Oladejo Okediji àti ìgbé ayé ìtàn kíkọ rẹ̀

  Àrá, ọ̀rẹ́, àwọn òǹkọ̀wé àti Mọ̀lẹ́bí olóògbé Oladejọ Okediji ń ṣe ìdáro bàbá tó yẹ kó ṣe ọjọ́ ìbí Àádọ́rùn ún ọdún láyé.

  Kà Síwájú Síi
  next