Eto Ọgbin

 1. Video content

  Video caption: Ilú òyìnbò ní mo lọ lásìkò Covid ló gún mi ni kẹ̀ṣẹ́ láti bẹ̀rẹ̀

  Oluwawemimo Tade, obìnrin àgbẹ̀ tó làmìlaaka jùlọ ní ìpínlẹ̀ Ondo ni kò si àwáwí fún ẹnikẹ́ni láti má ṣe iṣẹ́ àgbẹ̀

 2. Awọn Fulani

  Ẹgbẹ YCE fidi rẹ múlẹ pe ẹgbẹ kẹgbẹ tabi ẹya kẹya to ba wa nibi kibi ni Naijiria, lẹtọọ lati ni adari amọ wọn ko gbọdọ tabuku asa wa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Soiless Farming: Samson Ogbole ní táwọn irè oko bá fara kan ilẹ̀, ló ń kó àrùn bá wọn

  Samson Ogbole, agbẹ to n lo fulufulu eepo irẹsi lati sisẹ ọgbin lai lo erupẹ ba BBC Yoruba sọrọ lori ọna ti a le gba gbin eso ati ewebẹ yika ọdun.

 4. Video content

  Video caption: Fulani Herdsmen attack: Gbogbo ẹni tó bá para kò ní rí ojú 'rere Ọlọ́run, Fulani ló dá wa

  Awọn to ni iriri ikọlu Fulani sọ iriri wọn lodi si awọn iroyin ti ko fẹ fi oju Fulani han gẹgẹ bi aṣebi tori ofin ko gba wọn mu.

 5. Video content

  Video caption: Egbejila Fish Village: Àwọn ọlọ́sìn ẹja ní àwọn fi iṣẹ́ báńkì sílẹ̀ wá ṣe ọ̀sìn ẹja ni

  BBC Yoruba de abule ọ̀sin ẹ́ja nipinlẹ́ Kwara ati ọdọ ijọba ipinlẹ naa lati mọ ohun to fa aawọ laarin wọn lori ọsin ẹja to n waye leti odo Asa lagbegbe Egbejila nilu Ilorin.

 6. Video content

  Video caption: Erosion in Ilorin: Kòtò tó wà níbí jìn ju ilé ìgbẹ́ lọ́! Ẹ̀mí wa ò tiẹ̀ balẹ̀ mọ́

  Wọn ṣalaye pe bi awọn ọmọ ba ti wa nileewe bayii, wahala ni.