Itakun Agbaye

 1. MTN

  Atẹjiṣẹ lati ọwọ MTNCEO KARL ti awọn eeyan gba ṣaaju yii sọ pe ki awọn onibara wọn lọ wo fidio kan lọfẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Bamidele Muraina

  Laipẹ yii ni ẹka idajọ orilẹede Amẹrika fi ẹsun kan ọmọ Naijiria Ramomi Abass, ti ọpọ eniyan mọ si Hushpuppi pe o lu jibiti ori ayelujara.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Oba Tejuosho

  Wọn ni ẹsun jẹ nkan to doju ti gbogbo ilu ti wọn si fi kun pe Adetokunbo Tejuosho ko yẹ lẹni a yan sipo olori ilu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Paystack Shola Akinlade: Ìgbésẹ̀ 5 yìí ni mo gbé tíléeṣẹ́ Stripe fi dókòwò $200m pẹ̀lú mi

  Onimọ nipa eto idokowo lori ayelujara, to tun jẹ oludari ileesẹ Paystack Shola Akinlade salaye bo se lu aluyo lori ayelujara nidi okoowo fun BBC.

 5. Video content

  Video caption: Nigerian Fraudsters: Ìwádìí BBC fihàn pé ìdajì àwọn gbájúẹ̀ lágbàyéé wá láti Nàíjíríà

  Onijibiti ti BBC fọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wo ní òun fẹ́ lówó bíi olùdarí Facebook, Mark Zuckerberg ni òun ṣe ń lu jìbìtì.