Airiṣẹṣe

 1. SERAP

  SERAP fi ọrọ yii lede lasiko ti wọn gbe iwadii jade lori ẹsun iwa ibajẹ ni ẹka eto ilẹra, eto ẹkọ ati omi to n sakoba fun awọn ọmọ Naijiria kalẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Wikipedia: Ẹ̀nìkan sọ fún mi pé iṣẹ́ ìdọ̀tí ni màá ṣe ni mo ṣe ń ta ìwé

  BBC Yoruba se alabapade ọkunrin kan, Adekola Ademuyiwa, ẹni to sọ awọn iriri rẹ nidi iwe tita lọ̀na awada ati ẹfẹ ati awọn iwọsi to wa nidi okoowo naa.

 3. Video content

  Video caption: Silas Robotic Engineer: Kò sí ǹkan rere tí ọmọ Nàìjíríà kò lè ṣe

  Silas Adekunle to n ṣe awọn rọ́bọ̀ọ̀tì káàkiri agbaye ṣàlàyé ìrìnàjo rẹ̀ láti Ọdẹ Òmu lọ Ẹdẹ lọ Oṣogbọ dé UK.

 4. Aarẹ Buhari nipinlẹ Plateau

  Lasikọ ifọrọwanilẹnuwo lori eto ileeṣẹ amounmaworan ni aarẹ ti ni awọn ọdọ ni lati ṣe jẹjẹ ti wọn ba fẹ ri iṣẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. UK

  Igbesẹ yii n waye pẹlu bi ijọba orilẹede Gẹẹsi ṣe n gbaradi lati ṣi papakọ ofurufu rẹ silẹ fun Irinajo silẹ okeere.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Video content

  Video caption: Pure Water Lylon Art: Adejoke ní ohun èlò ta fi ọ̀rá ṣe ń ní àlòpẹ́, kìí tètè jẹ

  Adejoke Lasisi ni amulo ọra atawọn asọ aloku fun ipese ohun mere-mere n pese isẹ oojọ, to si n mu ki ọrọ aje ru gọgọ si.

 7. NLC

  Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ ni Naijiria ti ni awn yoo bẹrẹ ifẹhọnu tako igbese awọn asofin lati yi aṣẹ gbedeke owo oṣu oṣiṣẹ pada.

  Kà Síwájú Síi
  next