Aabo fun ẹrọ ayarabi asa

 1. Lai

  Ijọba jẹ ko di mimọ pe gbogbo ọrọ to fa sababi gbigbe òté lee lori lawọn ti n wa ojutu si ni lọọlọ yii to si ni ipadabọ Twitter yoo to de.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Bamidele Muraina

  Laipẹ yii ni ẹka idajọ orilẹede Amẹrika fi ẹsun kan ọmọ Naijiria Ramomi Abass, ti ọpọ eniyan mọ si Hushpuppi pe o lu jibiti ori ayelujara.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Kaadi NIN

  Ọpọ eeyan lo n tiraka lati gba aapu lori ayelujara fun iforukọsilẹ NIN wọn eyi to le se akoba fun wọn, ti wọn ba gba ayederu aapu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Nigerian Fraudsters: Ìwádìí BBC fihàn pé ìdajì àwọn gbájúẹ̀ lágbàyéé wá láti Nàíjíríà

  Onijibiti ti BBC fọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wo ní òun fẹ́ lówó bíi olùdarí Facebook, Mark Zuckerberg ni òun ṣe ń lu jìbìtì.