Ipinlẹ Akwa Ibom

 1. Afurasi ti wọn lo lu iyawo rẹ pa

  Ninu atẹjade to fi sita, agbenusọ ileesẹ ọlọpaa nipinlẹ naa, Odiko Macdon sọ pe ọjọ kẹrindinlogun, oṣu Kẹfa, ọdun 2021, ni ọwọ tẹ pasitọ, ẹni ọdun mọkandinlaadọta ọhun

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Mí ò tí gba àbẹ́tẹ́lẹ̀ rí ní ọgbsn ọdún ti mo fi ṣíṣẹ́ ọlọ́pàá- CSP Francis Osagie

  "Ibanujẹ ọkàn ló jẹ́ fún mi láti rí àwọn ọmọ tó wọ iṣẹ́ lẹ́yìn mi tí wọ́n sì ń gba ìgbéga, odidi ọgbọ̀n ọdún ni mo fi ṣòfò".

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Deborah Okezie

  Ijọ Deeper Life ati Pasitọ Kumuyi di ọrọ to n lọ lori ayelujara nitori ẹsun ifipabanilopọ to waye nile iwe rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Akwa-Ibom:Mílíọ́nù mẹ́wàá Náírà ni ilé ẹjọ́ ni kí Kábíyèsí san fún owó ìtaran ilẹ̀ tí ó gbà lọ́nà àìtọ́

  Nínú ìgbẹ́jọ́ ìgbìmọ̀ ẹlẹni mẹ́ta sàlàyé pé, ilé ẹjọ́ gíga kùnà, bi ó ṣe kọ̀ láti gba ẹrí tí wọ́n mú wá sílé ẹjọ́.

  Kà Síwájú Síi
  next