Orilẹede Libya

 1. Video content

  Video caption: African Eye: Ìwádìí BBC lórí ikú tó pa ọmọ ogun 26 ní Libya láti ipasẹ̀ Díróònù àìmọ̀dí

  BBC Africa Eye ṣe àwárí rẹ̀ pé, ilẹ̀ United Arabi Emirate UAE ati Egypt lo n fi diroonu sere ọwọ lorilẹede Libya, eyi ti ko jẹ ki ogun sinmi nibẹ.

 2. Awọn aṣatipo lori okun

  Awọn mẹtadinlọgbọn tawọn apẹja doola ẹmi wọn ṣalaye pe, awọn ọmọde marun un wa lara awọn to bomi lọ́nà àtilọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Aarẹ Buhari atawọn minisita

  Àèrẹ orílẹ̀eèdè Naijiria, Muhammadu Buhari ti sọ pé iṣẹ́ ibi àwọn alákatakítí ẹ̀sìn ni ìṣòro gbòógì tń ń kojú ìwọ̀ oòrùn Afrika.

  Kà Síwájú Síi
  next